Skip to main content

Ki ni verdaccio?

Verdaccio jẹ ibi iforukọsilẹ aṣoju ikọkọ npm aladani fifuyẹ to jẹ kikọ ni Node.js

logo

Kini n jẹ ibi iforukọsilẹ

 • Ibi ipamọ kan fun awọn akopọ ti o n ṣe imuṣiṣẹ alaye CommonJS Compliant Package Registry fun kika alaye akopọ
 • Pese API kan to ni ibamu pẹlu awọn onibara npm (yarn/npm/pnpm)
 • Semantic Versioning compatible (semver).
$> verdaccio

registry

Using Verdaccio

Using Verdaccio with any Node.js package manager client is quite straightforward.

registry

You can use a custom registry either by setting it globally for all your projects

npm set registry http://localhost:4873

or by using it in command line as an argument --registry in npm (slightly different in yarn)

npm install lodash --registry http://localhost:4873
yarn config set registry http://localhost:4873

Private

All packages that you publish are private and only accessible based in your configuration.

Proxy

Verdaccio cache all dependencies on demand and speed up installations in local or private networks.

In a Nutshell

 • O jẹ ohun elo ayelujara ti o da lori Node.js
 • O jẹ ibi iforukọsilẹ npm ti ikọkọ kan
 • O jẹ aṣoju ikọkọ nẹtiwọki ibilẹ kan
 • O jẹ ohun elo alaasomọ kan
 • O rọrun lati fi sori ẹrọ ati lati lo
 • A pese atilẹyin Docker ati Kubernetes
 • O ni ibamu 100% pẹlu yarn, npm ati pnpm
 • O jẹ fifayọ dida lori sinopia@1.4.0 ati 100% ibasisẹpọ ẹlẹyin.