Skip to main content

Ṣiṣe agbedide Awọn ohun elo

Awọn ọna pupọ lo wa lati fa verdaccio gun si, iru awọn ohun elo ti atilẹyin wa fun ni:

A ṣe igbaniyanju agbedide awọn ohun elo afikun nipa lilo awọn itumọ iru ilana wa.

Other plugins

Ni pataki julọ a ni lati da ohun kan pada pẹlu ọna kan ti a n pe ni ifasẹsi ti o ma gba awọn ariyanjiyan mẹta (olumulo, ọrọ igbaniwọle, ipe pada).

Theme Plugin

The plugin must return a function that returns a string. The string should be the absolute location of the root of your user interface.

API

const path = require('path');

module.exports = (...arguments) => {
return path.join(__dirname, 'static');
};

apiJWTmiddleware jẹ sisafihan lori PR#1227 lati le ni iṣakoso ti olutọju aami ni kikun, fifagbara bori ọna yii ma yọ atilẹyin login/adduser. A ṣe igbaniyanju pe ki o ma se ṣe amulo ọna yii ayafi ti o ba pọn dandan. Wo apẹẹrẹ ni kikun kan nibi.

Theme Example

Filter Plugin

Lọgan ti ifasẹsi naa ti waye awọn aṣayan meji lo wa lati fun verdaccio ni esi.

Boya a jẹ wipe ohun buburu kan sẹlẹ tabi ifasẹsi ko jẹ aṣeyọri.

Ifasẹsi naa jẹ aṣeyọri.

callback(null, false)

API

awọn ẹgbẹ jẹ oriṣi eto ti awọn okun nibi ti olumulo naa ti jẹ ara ti.

Do not remove properties from the metadata, try to do not mutate rather return a new object.

interface IPluginStorageFilter<T> extends IPlugin<T> {
filter_metadata(packageInfo: Package): Promise<Package>;
}